Diẹ ninu awọn Iranti Ọlọhun Ojoojumọ lati ọdọ Anabi Muhammad – Dr. Mubarak Zakariya Al imam – Hamid Yusuf
Iranti Ọlọhun jẹ ọkan pataki ninu awọn asẹ ti Ọlọhun pa fun awa onigbagbọ ododo, ti O si fẹ ki a maa se ni ọpọlọpọ asiko, Ọlọhun sọpe: (ẹyin onigbagbọ ododo, ẹ maa ranti Ọlọhun ni ọpọlọpọ.) [suurat ahzaab: 41]. Eyi tumọ si wipe, Ọlọhun fẹ ki a maa fiContinue Reading