Idajo ki eniyan to ni iduro – Rafiu Adisa Bello
2019-04-14
IBEERE (Ibeere alakoko fatwa 2001): Nje o leto ki eniyan to ni iduro bi? IDAHUN: Ope ni fun Olohun, ike ati ola fun Ojise Olohun ati awon ara ile re. Kiise eewo ki eniyan to ni iduro, sugbon sunna ni o je ki eniyan bere ti o ba fe to. IyaContinue Reading