Yiyapa Ilana Awọn Asiwaju Ninu Ẹsin Nibi Itumọ Alukurani jẹ Okunfa Isina – Rafiu Adisa Bello
2019-04-14
Ninu awọn ohun ti o jẹ ojuse fun Musulumi, ti o si jẹ dandan fun un ni ki o maa tẹle ilana awọn ẹni isaaju ninu ẹsin, ki o maa rin lori ilana wọn, ki o si mase yapa si wọn. Eleyi ri bẹẹ nitoripe awọn ni asiwaju ninu ẹsinContinue Reading