DIẸ NINU ADISỌKAN AWỌN ALASEJU NINU AWỌN SUUFI – Rafiu Adisa Bello – Hamid Yusuf – Abdul-hamiid Osiofit
2019-04-14
Alakọkọ: Adisọkan wọn nipa OjisẹỌlọhun: Orisirisi adisọkan ni awọn alaseju ninu awọn suufi ni si ojisẹ Ọlọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], o nbẹ ninu wọn ẹniti o gba wipe ojisẹ Ọlọhun ko de ipo ti awọn de atipe ko ni imọ ijinlẹ ti awọn waliyyiContinue Reading