Itumo Gbolohun (As-salaf) – Rafiu Adisa Bello
2019-04-14
Itumo gbolohun “as-salaf” ninu ede ni eni ti o ba je asiwaju fun eniyan ti o julo pelu ojo ori ati ipo. Idi niyi ti o fi je wipe gbogbo itumo ti awon onimimo esin maa n fun gbolohun “as-salaf” ko ye kuro lori awon nkan meta wonyi: Alakoko: AwonContinue Reading