Dandan ni fun Musulumi lati maa seri si ibi Al-kurani ati Sunna lori oro Esin – Rafiu Adisa Bello
2019-04-14
Siseri sibi Al-kurani ati sunna ati diduro sinsin pelu won ni okunfa ola ati oriire fun gbogbo ijo Musulumi patapata, ohun naa ni o si je iso fun won kuro nibi orisirisi adanwo, nitoripe gbogbo aburu patapata ohun ti o n se okunfa re naa ni gbigbunri kuro nibi esinContinue Reading