Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni – Rafiu Adisa Bello
2019-04-14
Olohun- ti ola Re ga- so wipe: (Dajudaju A o siju wo ohun ti won se ni ise, A o wa so o di eruku ti a ku danu) [Suuratu Furkooni: 23]. Alaye Lori Aayah Yi: Olohun- Oba mimo Oba ti o ga- nso ninu aayah yi nipa awon osebo,Continue Reading