Ninu Awon Eko Irinajo Fun Ise Haj Tabi Umrah – Rafiu Adisa Bello
Gbogbo ohun ti esin Islam pa awa Musulumi ni ase re ni o ni ilana, eto ati eko ti o ti gbe kale fun awon nkan naa. Irinajo lo si ilu Makkah fun ise Haj je origun kan ti o se pataki ninu awon origun esin Islam. Haj ni origunContinue Reading