Kinni onjẹ okun ibi tabi ẹbi rẹ? Okun ẹbi ni awọn ohunti o so awọn eniyan papọ, gẹgẹ bii iya ati baba, iya iya ati baba baba, ọmọọkunrin tabi obinrin, awọn ẹbi baba ati iya, bakanna ni okun ibi nbẹ laarin ẹgbọn si aburo, laarin ọmọ iya kan naa ,Continue Reading