Se pẹlu agbara ni o yẹ ki a fi bẹrẹ lati se atunse iwa ti ko dara bi? – Sheikh Muhammad Sọọlih Al-munajjid – Rafiu Adisa Bello – Hamid Yusuf
2019-04-14
IBEERE ATI IDAHUN LORI ỌRỌ ẸSIN ISLAM (FATWA 10522) IBEERE: Ti a ba se akiyesi iwa tabi isesi ti ko dara, se pẹlu agbara ni o yẹ ki a fi bẹrẹ lati se atunse rẹ bi? Se itumọ hadiisi ti o sọ wipe: (Ẹniti o ba ri nkan ti koContinue Reading