Ibeere (Fatwa [36766]): Njẹ o wa ni akọsilẹ wipe ọla kan nbẹ fun sise isẹ Umrah ninu osu Rajab bi? Idahun: Ọpẹ ni fun Ọlọhun. Alakọkọ: ko si akọsilẹ kankan ti o fi ẹsẹ mulẹ lati ọdọ ojisẹỌlọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] lori wipe ọlaContinue Reading