Gbogbo eyin je ti Olohun, Eni ti I se Oba gbogbo aye. Ki ike ati ola si ma a je ti asiwaju gbogbo awon ojise Anabi wa Muhammad ati awon ara ile re pelu awon alabarin (sohaabah) re ni apapo. Lehin – wa igba – naa, esin ISLAM: ohun niContinue Reading

ITOKASI Oro akoso: ————————————— 1 Leta kinni: ————————————– 4 Bi ati nse Umrah: ——————————- 6 Awon ise Haji: ———————————11 Sise abewo Ilu Modinah: ——————– 16 leta keji: —————————————- 19 leta keta: ————————————— 34 leta kerin: ————————————– 53 leta karun: ————————————– 60 leta kefa: —————————————- 73 leta keje: —————————————- 82 letaContinue Reading

Alaye-ondiwon-zakat-nisob-ninu-awon-eran-osin-lo-bayi

ATỌKA Koko Ọrọ Oju ewe 1 Ọrọ Isãju 2 Origun-kinin: Ijẹri pe ko si ẹniti a gbọdọ jọsin fun ni ododo afi Ọlọhun, ati pe (Annabi) Muhammad ojişẹ Ọlọhun ni 3 Awọn Mọjẹmu Gboloun Taoheed (Imọ Ọlọhun l’ọkan) 4 Itumọ rẹ: Taoheedul Uluiyat 5 Awọn orukọ rẹ 6 Idajọ rẹContinue Reading