Itumo ati Pataki Ijeri Mejeeji (LA ILAHA ILLA ALLAH, MUHAMMADU ROSUULU LLAH) – Rafiu Adisa Bello
Alakoko: Itumo (LA ILAHA ILLA ALLAH): Itumo ijeri yi ni ki eniyan gba pelu okan re pe kosi eni kankan ti o leto si ijosin ni ti ododo ayafi Olohun Allah nikan soso, kosi orogun fun Un ninu awon ijosin ti a nse fun Un, beeni kosi orogun fun UnContinue Reading