Ilu lilu nibi inawo tabi ajoyọ ko ba Ẹsin Islam mu – Sheikh Muhammad Sọọlih Al-munajjid – Rafiu Adisa Bello – Hamid Yusuf
IBEERE ATI IDAHUN LORI ỌRỌ ẸSIN ISLAM (FATWA 12929) IBEERE: Kinni idajọ lilọ si ibi apejẹ tabi ajọyọ, ti awọn nkan ti ko ba ẹsin Islam mu gẹgẹ bii lilu ilu wa nibẹ, ti o si jẹ wipe ẹniti o pepe si apejẹ naa jẹ ọkan ninu awọn alasunmọ ẹni,Continue Reading