Itumọ Wiwa Alubarika ati Awọn Ipin rẹ – Rafiu Adisa Bello
Ohun ti a npe ni alubarika ni oore ti o pọ, ti o si pe lọwọẹniti Ọlọhun Allah ba fun. Itumọ ki eniyan maa fi nkankan wa alubarika ni ki o maa lo nkan ti Ọlọhun pe ni okunfa alubarika lati maa fi wa a. Ninu ohun ti o jẹContinue Reading