Gbogbo eyin je ti Olohun, Eni ti I se Oba gbogbo aye. Ki ike ati ola si ma a je ti asiwaju gbogbo awon ojise Anabi wa Muhammad ati awon ara ile re pelu awon alabarin (sohaabah) re ni apapo. Lehin – wa igba – naa, esin ISLAM: ohun niContinue Reading