NJE A LE RI ANABI MUHAMMAD NI OJU ALA – Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi
2019-04-14
NJE A LE RI ANABI NI OJU ALA? Ni otito, eniyan le ri anabi Muhammad-alaafia Olohun fun un – ni oju oorun. Sugbon Shatani le pe ara re ni anabi gege bi ero okan wa se le yipada si ohunkohun nigbati a ba ti sun. Nipase bee, riri anabi lojuContinue Reading