Awọn ohun ti o yẹ ki musulumi o mọ, ki o si maa se ni Ọjọ jimoh – Dr. Mubarak Zakariya Al imam – Hamid Yusuf
OHUN TI O YẸ KI MUSULUMI O MỌ NIPA ỌJỌ JIMỌH. Ninu iwe yi, a o sọọrọ nipa ọla ati ajulọ ti o wa fun ọjọ jimọh ati pataki ọjọ naa ati awọn isẹ ti oyẹ ki a se ninu rẹ. ALAKỌKỌ: PATAKI ỌJỌ JIMOH. Ọjọ jimọh jẹọkan pataki ninuContinue Reading