OOrun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo
“النَّبِيُّ أَوْلَى بِالْمُؤْمِنِينَ مِنْ أَنفُسِهِمْ وَأَزْوَاجُهُ أُمَّهَاتُهُمْ” (الأحزاب6) Anabi ni eto si awon oni gbagbo ododo ju ara won lo, atipe awon iyawo re ni awon iya won (Suratul- Ahzaab: 6) Oro isiwaju – Alaye soki nipa, awon iya awon olugbagbo ododo Ope ni fun Olohun, ike ati ola fun eniContinue Reading