Idajọ Ẹsin Islam lori Didaabo bo Ẹmi ara ẹni – Sheikh Muhammad Sọọlih Al-munajjid – Rafiu Adisa Bello – Hamid Yusuf
2019-04-14
IBEERE ATI IDAHUN LORI ỌRỌ ẸSIN ISLAM IBEERE: Kinni idajọẹsin Islam lori didaabo bo ẹmi ara ẹni? Se ninu awọn ẹtọ ni o wa? Se awọn ẹtọ yi si ni majẹmu? Bakanna, seAlukuraani n sọọrọ nipa idaabo bo ẹmi ara ẹni? FATWA [21932] IDAHUN: Ọpẹ ni fun Ọlọhun. Didaabo boContinue Reading